[Lyrics] Igba Mi Tire Ni – Sola Allyson

Chorus

Igba mi tire ni (2x)
Aye mi yi o ma bu ola fun o ni igba gbogbo
Igba mi tire ni

Whatever it is,
Igba mi tire ni
Whatever may come,
Igba mi tire ni
Imole a maa tan si ona mi ni igba gbogbo
Igba mi tire ni

Igba mi tire ni
Irin ti mo n rin, tire ni
Aiye mi yi o ma bu ola fun o ni igba gbogbo
Igba mi tire ni
Iwo se olododo
Iwo je olododo
Aiye mi yi o ma so be ni igba gbogbo
Iwo je olododo
Iwo ni alaanu
Alaanu ni oruko re
Aiye mi yo ma fi han be ni igba gbogbo
Alaanu ni oruko re
Mo mo o ni alaanu
Anu re lo gbe mi ro
Bi o se yen tani emi
Oba to fi aanu yo mi ninu okunkun
Ogo fun oruko re
Imole a ma tan si ona mi ni igba gbogbo
Emi mi tire ni
Gbogbo oun ti mo je tire ni
Ogo aye mi a maa bu ola fun o ni igba gbogbo
Gbogbo ogo pada sodo re

Chorus

Wa fi mi han gege bi tire
Nipase aye mi, awon eniyan won a wa sodo re
Aiye mi yi o ma bu ola fun o ni igba gbogbo
Igba mi tire ni
I give myself to you oluwa
I pour my all to you eni ti o ni emi mi
Aiye mi yi o maa bu ola fun ni igba gbogbo
Igba mi tire ni
Okunkun to wa lona mi, imole tan nbe
Aye mi tireni
Egun to wa lona mi, oka kuro iture wa nibe
Igba mi tire ni
I have chosen to give my life to you
Ore ofe ko ba lemi lati odo re
Gbe mi ro kin rin irin ajo yii ja, kin la ajo yi ja fun ogo re
Igba mi tire ni
Eni to ri mi, iwo ni ko ma ri oluwa
Eni ti gbo mi ko maa gbo o ni igba gogbo
Eni ti owa si odo mi, odo re ni ki won wa oluwa
Igba mi tire ni
Ohun ti mo nilo fifun mi oluwa
Aiye mi tire eni
Baba mi ati olorun mi
Igba mi tire ni
O se olododo. ododo re ki ye
Nevertheless iwo ni oluwa
Regardless whatever it is iwo ni oluwa
Igba mi tire ni
Iwo ti o mumi debi wa sun mi si iwaju
Sibe sibe odo re ni mo duro si
Ko si ohun to le ya mi ya o Jesu oluwa
Igba mi tire ni
Baba imole to tan imole si ona mi
Jesu imole mi ki o ma tan si ni igba gbogbo
Fi ara re han mi si jesu oluwa
Igba mi tire ni
Jesu omo olorun otito ati iye
Fi ara re han mi si
Kin se bi aye fi han ni
Imole re ko tan si ona ni ni igba gbogbo

Previous article[Music Lyrics] Only You | Kida Praise Crew
Next article[Lyrics] Overflow – David’s Heart Ft. Naomi Classik