NgospelMedia.Net
NgospelMedia.net is The No. 1 International Urban Gospel Media Website, The Largest Repository of Your Favorite Gospel Entertainment Website, Worldwide, Nigeria. We Published Latest Nigerian and Foreign Gospel Music Downloads, Videos; Lyrics, Artiste Biography, Daily Devotionals. NgospelMedia is mainly a Christian Website, as the Domain Name Speaks; Gospel; Which is also tagged as a Gospel On-line Ministry for Souls Winning... 

Ride On Remix By Monique ft Mike Abdul Full Lyrics & Video

0 109

Song Artiste: ,
Artiste Country Origin:
Song Language: ,
Music Genres:
Music Group:
Artiste Musical Album:

- Advertisement -


SONG TITLE: Ride On (Remix)

Ride On Remix By Monique ft Mike Abdul Full Lyrics & Video

[Verse 1]
Agbára Olórun mbe Níbí
The Power of God is here
Èmí Olórun mbe Níbí
The Spirit of God is here

[Chorus]
Momòpé bímobá képè é,
Óma foùn
Momòpé bímobá kpérè é,
Á sògo.
I know that the Spirit of God
Will cause an Overflow
Ride On, Ride On, Ride On
Èmí Ooh
Ride On, Ride On, Ride On

[Repeat Verse 1]
Agbára Olórun mbe Níbí
The Power of God is here
Èmí Olórun mbe Níbí
The Spirit of God is here

Read More:  [Music + Lyrics + Video] Jesus Is The Answer (Live) - Osita Peter {Free Download}

[Chorus]
Momòpé bímobá képè é,
Óma foùn
Momòpé bímobá kpérè é,
Á sògo.
I know that the Spirit of God
Will cause an Overflow
Ride On, Ride On, Ride On
Èmí Ooh
Ride On, Ride On, Ride On

[Verse 2]
Let my Ears belong to you
So all I Hear is you
Let my Heart belong to you
(Let my Heart belong to you)
So all I do is you
Shield me from the Power of sin
Let them got nothing on me.
Holy Spirit, Gbàmí tán

[Chorus]
(Momòpé bímobá képè é,
Óma foùn
Momòpé bímobá kpérè é,
Á sògo.
I know that the Spirit of God
Will cause an Overflow
Ride On, Ride On, Ride On
Èmí Ooh
Ride On, Ride On, Ride On) [x2]

[Spontaneous]
Agbára Olórun mbe láyé mi
Agbára tóh borí ohun gbogbo
Who art thou oh mountain
Níwájú Oba gbogbo ayé
Olúwa tóh pò nípá àti agbára
Òkan soso òrò tí nso gbogbo òrò
Òrò gbénú omi adágún
Òrò gbénú omi òkun ru
Ìjìnlè nlá Atófaratì bí òkè
Mopá tàsetàse L’órúko JÉSÙ Kristì
Egbé oríiyín sókè, èyin

Read More:  I Will Worship - Just Davies

Enu ònà, kí asì gbé e yín sókè èyin
Ilèkùn ayérayé, kí Oba ògo
Kíó wolé wá
Àkóbí nú àwon òkú, òdó àgùntàn
Tíó fèmí rè lé’lè fún wa
Olùdámòràn, igi òkìkí,
àpáta aìí dìgbòlù, òkè táò l’esí
Òjìjí àti ìmólè

THE VIDEO

- Advertisement -

Subscribe to our newsletter
Sign up here to get the latest news, updates and special offers delivered directly to your inbox.
You can unsubscribe at any time

- Advertisement -

- related posts -

0 0 votes
Article Rating
Subscribe
Notify of
guest
0 Comments
Inline Feedbacks
View all comments
0
Would love your thoughts, please comment.x
()
x
Send this to a friend